[GUEST ACCESS MODE: Data is scrambled or limited to provide examples. Make requests using your API key to unlock full data. Check https://lunarcrush.ai/auth for authentication information.]  Arojinle [@arojinle1](/creator/twitter/arojinle1) on x 188K followers Created: 2025-06-01 16:56:51 UTC Here are some I can think of right now: Ẹkùn - Leopard Kìnìún - Lion 🦁 Àmọ̀tẹ́kùn - Cheetah 🐆 Ìkookò - Spotted hyena Ẹtà / Ọlọ́gẹ̀dẹ̀ - African civet Eerin - Elephant 🐘 Ehoro - Hare Ikún - Ground squirrels Ọ̀kẹ́rẹ́ - Squirrel 🐿️ Ọ̀wàwà - Tree hyrax Àjàò - Flying squirrel Igúnnugún - Vulture Òdèrée Kókò - Laughing dove Ẹyẹlé - Pigeon 🐦 Òwìwí - Owl 🦉 Àdàbà - Dove 🕊️ Pẹ́pẹ́yẹ - Duck 🦆 Tòlótòló - Turkey 🦃 Adìẹ - Hẹn/Chicken Àkùkọ́ - Cock/Rooster 🐓 Ògòǹgò - Ostrich Àgùfọn - Giraffe 🦒 Àfèrèmọ̀jò - Aardvark Akika - Pangolin Ìrá - Hartebeest Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ - Donkey Ẹṣin - Horse 🐎 Ẹfọ̀n - Buffalo 🐃 Ìgbàrìgbá - Rhinoceros 🦏 Erinminlókun - Hippopotamus 🦛 Ìnàkí - Gorilla 🦍 Irò/ Elègbèdè - Chimpanzee Ìlábùrù - Baboon Àdán - Bat 🦇 Yímíyímí - Dung beetle Àrígiṣẹ́gi - Bagworm moth Kúlúsọ - Antlion larvae Ìmúùmúná - Firefly Aláǹtakùn - Spider 🕷️ Ẹ̀fọn - Mosquito 🦟 Àkekèé - Scorpion Ìdun - Bedbug Ikán - Termite Ìjàlọ - Army ant Ọká - Gaboon viper Mọ́námọ́ná - Ball python Erè - African rock python Paramọ́lẹ̀ - Puff adder Líìlí - Hedgehog 🦔 Òòrẹ̀ - Porcupine Ìmàdò - Warthog Túrùkú - Red river hog Adárípọ́n - Agama Lizard Ọ̀gà - Chameleon Wall gecko - Ọmọńlé/ Ọmọ onílé Ọ̀ọ̀nì - Crocodile Ẹlẹ́gungùn - African dwarf crocodile XXXXXXX engagements  **Related Topics** [top 50](/topic/top-50) [owl](/topic/owl) [dove](/topic/dove) [dre](/topic/dre) [elephant](/topic/elephant) [Post Link](https://x.com/arojinle1/status/1929220611210940706)
[GUEST ACCESS MODE: Data is scrambled or limited to provide examples. Make requests using your API key to unlock full data. Check https://lunarcrush.ai/auth for authentication information.]
Arojinle @arojinle1 on x 188K followers
Created: 2025-06-01 16:56:51 UTC
Here are some I can think of right now:
Ẹkùn - Leopard Kìnìún - Lion 🦁 Àmọ̀tẹ́kùn - Cheetah 🐆 Ìkookò - Spotted hyena Ẹtà / Ọlọ́gẹ̀dẹ̀ - African civet Eerin - Elephant 🐘 Ehoro - Hare Ikún - Ground squirrels Ọ̀kẹ́rẹ́ - Squirrel 🐿️ Ọ̀wàwà - Tree hyrax Àjàò - Flying squirrel Igúnnugún - Vulture Òdèrée Kókò - Laughing dove Ẹyẹlé - Pigeon 🐦 Òwìwí - Owl 🦉 Àdàbà - Dove 🕊️ Pẹ́pẹ́yẹ - Duck 🦆 Tòlótòló - Turkey 🦃 Adìẹ - Hẹn/Chicken Àkùkọ́ - Cock/Rooster 🐓 Ògòǹgò - Ostrich Àgùfọn - Giraffe 🦒 Àfèrèmọ̀jò - Aardvark Akika - Pangolin Ìrá - Hartebeest Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ - Donkey Ẹṣin - Horse 🐎 Ẹfọ̀n - Buffalo 🐃 Ìgbàrìgbá - Rhinoceros 🦏 Erinminlókun - Hippopotamus 🦛 Ìnàkí - Gorilla 🦍 Irò/ Elègbèdè - Chimpanzee Ìlábùrù - Baboon Àdán - Bat 🦇 Yímíyímí - Dung beetle Àrígiṣẹ́gi - Bagworm moth Kúlúsọ - Antlion larvae Ìmúùmúná - Firefly Aláǹtakùn - Spider 🕷️ Ẹ̀fọn - Mosquito 🦟 Àkekèé - Scorpion Ìdun - Bedbug Ikán - Termite Ìjàlọ - Army ant Ọká - Gaboon viper Mọ́námọ́ná - Ball python Erè - African rock python Paramọ́lẹ̀ - Puff adder Líìlí - Hedgehog 🦔 Òòrẹ̀ - Porcupine Ìmàdò - Warthog Túrùkú - Red river hog Adárípọ́n - Agama Lizard Ọ̀gà - Chameleon Wall gecko - Ọmọńlé/ Ọmọ onílé Ọ̀ọ̀nì - Crocodile Ẹlẹ́gungùn - African dwarf crocodile
XXXXXXX engagements
/post/tweet::1929220611210940706